HRH Oba Sikiru Kayode Adetona
April 2nd, 1960.
A new king was enthroned in Ijebuland. Kabiyesi Oba Sikiru Kayode Adetona, Ogbagba II became the 56th Awujale of Ijebuland.
A new king was enthroned in Ijebuland. Kabiyesi Oba Sikiru Kayode Adetona, Ogbagba II became the 56th Awujale of Ijebuland.
I join millions of Ijebu indigenes in congratulating our king on the 54th Anniversary of his coronation.
Kabiesi, Ade ape lori, bata apel'ese, irukere a pe l'owo.
Awujale, omo arojo joye, omo alagemo ogun woyowoyo, Omo aladiye ogogomoga, omo adiye balokun omilili, ara orokun, ara o radiye, omo ohun seni oyoyonyo, oyoyo mayomo ohun seni olepani, omo dudu ile komobe se njosi, pupa tomo be se okuku sinle, omo moreye mamaroko, morokotan eye matilo, omo moni isunle mamalobe, obe tin benile komoile baba tobiwan lomo,Omo onigbo ma’de, omo onigbo mawo mawo, omo onigbo ajoji magbodowo, ajoji tobawo gboro yio di ebora ile baba tobi wan lomo. Ijebu omo ere niwa, omo olowo isembaye, towo kuji to dode, koto dowo eru, koto dowo omo. Orisa jendabi onile yi, niwan finpe igba ijebu owo, kelebe ijebu owo, ito ijebu owo, dudu ijebu owo, pupa ijebu owo, kekere ijebu owo, agba ijebu owo. Ijebu ode ijebu ni, ijebu igbo ijebu ni, ijebu isara ijebu ni, ayepe ijebu, ikorodu ijebu ijebu noni, Ijebu Omo Oni Ile nla, Ijebu Omo Alaso nla! Ajuwaase ooo"
No comments:
Post a Comment